Sek 3:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si wi fun Satani pe, Oluwa ba ọ wi, iwọ Satani; ani Oluwa ti o ti yàn Jerusalemu, o ba ọ wi: igi iná kọ eyi ti a mu kuro ninu iná?

Sek 3

Sek 3:1-10