Sek 13:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe, ni gbogbo ilẹ, li Oluwa wi, a o ké apá meji ninu rẹ̀ kuro yio si kú; ṣugbọn apá kẹta yio kù ninu rẹ̀.

Sek 13

Sek 13:7-9