Sek 10:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si gbìn wọn lãrin awọn enia: nwọn o si ranti mi ni ilẹ jijin; nwọn o si wà pẹlu awọn ọmọ wọn, nwọn o si tún pada.

Sek 10

Sek 10:3-12