Sef 3:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori nigbana li emi o yi ède mimọ́ si awọn enia, ki gbogbo wọn ki o le ma pè orukọ Oluwa, lati fi ọkàn kan sìn i.

Sef 3

Sef 3:5-13