Sef 3:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kọrin, iwọ ọmọbinrin Sioni; kigbe, iwọ Israeli; fi gbogbo ọkàn yọ̀, ki inu rẹ ki o si dùn, iwọ ọmọbinrin Jerusalemu.

Sef 3

Sef 3:7-20