Rut 4:20-22 Yorùbá Bibeli (YCE)

20. Amminadabu si bi Naṣoni, Naṣoni si bi Salmoni;

21. Salmoni si bi Boasi, Boasi si bi Obedi;

22. Obedi si bi Jesse, Jesse si bi Dafidi.

Rut 4