Rut 4:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ile rẹ ki o si dabi ile Peresi, ẹniti Tamari bi fun Juda, nipa irú-ọmọ ti OLUWA yio fun ọ lati ọdọ ọmọbinrin yi.

Rut 4

Rut 4:9-17