Rut 1:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si jade kuro ni ibi ti o gbé ti wà, ati awọn aya-ọmọ rẹ̀ mejeji pẹlu rẹ̀; nwọn si mu ọ̀na pọ̀n lati pada wá si ilẹ Juda.

Rut 1

Rut 1:1-12