Rom 9:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni kì iṣe pe, nitori nwọn jẹ irú-ọmọ Abrahamu, gbogbo wọn li ọmọ: ṣugbọn, Ninu Isaaki li a ó ti pè irú-ọmọ rẹ.

Rom 9

Rom 9:2-17