Rom 9:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. OTITỌ li emi nsọ ninu Kristi, emi kò ṣeke, ọkàn mi si njẹ mi li ẹrí ninu Ẹmí Mimọ́,

2. Pe mo ni ibinujẹ pupọ, ati ikãnu igbagbogbo li ọkàn mi.

Rom 9