Rom 8:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ofin Ẹmí ìye ninu Kristi Jesu ti sọ mi di omnira lọwọ ofin ẹ̀ṣẹ ati ti ikú.

Rom 8

Rom 8:1-11