Rom 6:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ẹ maṣe jẹ ki ẹ̀ṣẹ ki o jọba ninu ara kiku nyin, ti ẹ o fi mã gbọ ti ifẹkufẹ rẹ̀;

Rom 6

Rom 6:6-15