Rom 4:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ireti kò si, ẹniti o gbagbọ ni ireti ki o le di baba orilẹ-ède pupọ, gẹgẹ bi eyi ti a ti wipe, Bayi ni irú-ọmọ rẹ yio ri.

Rom 4

Rom 4:10-25