Rom 4:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bawo li a ha kà a si i? nigbati o wà ni ikọla tabi li aikọla? Kì iṣe ni ikọla, ṣugbọn li aikọla ni.

Rom 4

Rom 4:9-16