Rom 3:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun awọn Ju nikan ha ni bi? ki ha ṣe ti awọn Keferi pẹlu? Bẹ̃ni, ti awọn Keferi ni pẹlu:

Rom 3

Rom 3:20-31