Rom 15:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori Kristi pẹlu kò ṣe ohun ti o wù ara rẹ̀; ṣugbọn gẹgẹ bi a ti kọ ọ pe, Ẹ̀gan awọn ti ngàn ọ ṣubu lù mi.

Rom 15

Rom 15:1-8