Rom 15:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nisisiyi bi emi kò ti li àye mọ́ li ẹkùn wọnyi, bi emi si ti fẹ gidigidi lati ọdún melo wọnyi lati tọ̀ nyin wá,

Rom 15

Rom 15:21-29