Rom 15:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo du u lati mã wasu ihinrere na, kì iṣe nibiti a gbé ti da orukọ Kristi ri, ki emi ki o máṣe mọ amọle lori ipilẹ ẹlomiran.

Rom 15

Rom 15:16-23