Rom 14:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bi a ba wà lãye, awa wà lãye fun Oluwa; bi a ba si kú, awa kú fun Oluwa: nitorina bi a wà lãye, tabi bi a kú ni, ti Oluwa li awa iṣe.

Rom 14

Rom 14:4-18