Rom 14:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nitorina, ki awa ki o mã lepa ohun ti iṣe ti alafia, ati ohun ti awa o fi gbe ara wa ró.

Rom 14

Rom 14:9-23