Rom 14:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ijọba Ọlọrun kì iṣe jijẹ ati mimu; bikoṣe ododo, ati alafia, ati ayọ̀ ninu Ẹmí Mimọ́.

Rom 14

Rom 14:11-18