Rom 14:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori a ti kọ ọ pe, Oluwa wipe, Bi emi ti wà, gbogbo ẽkún ni yio kunlẹ fun mi, ati gbogbo ahọn ni yio si jẹwọ fun Ọlọrun.

Rom 14

Rom 14:1-19