Rom 13:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oru bukọja tan, ilẹ si fẹrẹ mọ́: nitorina ẹ jẹ ki a bọ́ ara iṣẹ òkunkun silẹ, ki a si gbe ihamọra imọlẹ wọ̀.

Rom 13

Rom 13:5-14