Rom 12:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ifẹ ki o wà li aiṣẹtan. Ẹ mã takéte si ohun ti iṣe buburu; ẹ faramọ́ ohun ti iṣe rere.

Rom 12

Rom 12:3-15