Rom 12:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Olufẹ, ẹ máṣe gbẹsan ara nyin, ṣugbọn ẹ fi àye silẹ fun ibinu; nitori a ti kọ ọ pe, Oluwa wipe, Temi li ẹsan, emi ó gbẹsan.

Rom 12

Rom 12:16-21