Rom 10:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ododo ti iṣe ti igbagbọ́ sọ bayi pe, Máṣe wi li ọkàn rẹ pe, tani yio goke lọ si ọrun? (eyini ni, lati mu Kristi sọkalẹ:)

Rom 10

Rom 10:1-10