Rom 10:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Isaiah tilẹ laiya, o si wipe, Awọn ti kò wá mi ri mi; awọn ti kò bère mi li a fi mi hàn fun.

Rom 10

Rom 10:16-21