Rom 10:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) ARÁ, ifẹ ọkàn mi ati adura mi si Ọlọrun fun Israeli ni, fun igbala wọn. Nitori mo gbà ẹri wọn jẹ pe