Rom 1:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn kún fun aiṣododo gbogbo, àgbere, ìka, ojukòkoro, arankan; nwọn kún fun ilara, ipania, ija, itanjẹ, iwa-buburu; afi-ọrọ-kẹlẹ banijẹ,

Rom 1

Rom 1:20-32