Owe 8:35-36 Yorùbá Bibeli (YCE)

35. Nitoripe ẹniti o ri mi, o ri ìye, yio si ri ojurere Oluwa.

36. Ṣugbọn ẹniti o ṣẹ̀ mi, o ṣe ọkàn ara rẹ̀ nikà: gbogbo awọn ti o korira mi, nwọn fẹ ikú.

Owe 8