Owe 7:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. ỌMỌ mi, pa ọ̀rọ mi mọ́, ki o si fi ofin mi ṣe ìṣura ṣura pẹlu rẹ.

2. Pa ofin mi mọ́, ki iwọ ki o si yè; ati aṣẹ mi bi ọmọloju rẹ.

Owe 7