Owe 30:19-21 Yorùbá Bibeli (YCE)

19. Ipa idì loju ọrun; ipa ejò lori apata: ipa ọkọ̀ loju okun; ati ìwa ọkunrin pẹlu wundia.

20. Bẹ̃ni ìwa agbere obinrin: o jẹun, o si nù ẹnu rẹ̀ nù, o si wipe, emi kò ṣe buburu kan.

21. Nitori ohun mẹta, aiye a di rũru, ati labẹ mẹrin ni kò le duro.

Owe 30