Owe 29:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn enia buburu ba npọ̀ si i, irekọja a pọ̀ si i: ṣugbọn awọn olododo yio ri iṣubu wọn.

Owe 29

Owe 29:12-20