Owe 28:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnikẹni ti o ba nrin dẽde ni yio là: ṣugbọn ẹniti o nfi ayidayida rìn loju ọ̀na meji, yio ṣubu ninu ọkan ninu wọn.

Owe 28

Owe 28:9-26