Owe 24:1-4 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. IWỌ máṣe ilara si awọn enia buburu, bẹ̃ni ki o má si ṣe fẹ lati ba wọn gbe.

2. Nitoriti aiya wọn ngbiro iparun, ète wọn si nsọ̀rọ ìwa-ika.

3. Ọgbọ́n li a fi ikọ ile; oye li a si fi ifi idi rẹ̀ kalẹ.

4. Nipa ìmọ ni iyará fi ikún fun oniruru ọrọ̀ iyebiye ati didùn.

Owe 24