Owe 21:30-31 Yorùbá Bibeli (YCE)

30. Kò si ọgbọ́n, kò si imoye, tabi ìgbimọ si Oluwa.

31. A mura ẹṣin silẹ de ọjọ ogun: ṣugbọn iṣẹgun lati ọwọ Oluwa ni.

Owe 21