Owe 11:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ododo awọn aduro-ṣinṣin yio gbà wọn là: ṣugbọn awọn olurekọja li a o mu ninu iṣekuṣe wọn:

Owe 11

Owe 11:4-12