Owe 10:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

OWE Solomoni ni wọnyi. Ọlọgbọ́n ọmọ ṣe inu-didùn baba rẹ̀, ṣugbọn aṣiwere ọmọ ni ibanujẹ iya rẹ̀.

Owe 10

Owe 10:1-3