Owe 1:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi nwọn wipe, Wá pẹlu wa, jẹ ki a ba fun ẹ̀jẹ, jẹ ki a lugọ ni ikọkọ de alaiṣẹ̀ lainidi.

Owe 1

Owe 1:5-15