Oni 3:6-9 Yorùbá Bibeli (YCE)

6. Ìgba wiwari, ati ìgba sísọnu: ìgba pipamọ́ ati ìgba ṣiṣa tì;

7. Ìgba fifaya, ati ìgba rirán; ìgba didakẹ, ati ìgba fifọhùn;

8. Ìgba fifẹ, ati ìgba kikorira; ìgba ogun, ati ìgba alafia.

9. Ere kili ẹniti nṣiṣẹ ni ninu eyiti o nṣe lãla?

Oni 3