Oni 3:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo wi li aiya mi niti ìwa awọn ọmọ enia; ki Ọlọrun ki o le fi wọn hàn, ati ki nwọn ki o le ri pe ẹran ni awọn tikalawọn fun ara wọn.

Oni 3

Oni 3:11-19