O. Sol 7:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jẹ ki a dide lọ sinu ọgba-àjara ni kutukutu; jẹ ki a wò bi àjara ruwe, bi itanná àjara ba là, ati bi igi granate ba rudi: nibẹ li emi o fi ifẹ mi fun ọ.

O. Sol 7

O. Sol 7:6-13