O. Sol 6:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mu oju rẹ kuro lara mi nitori nwọn bori mi: irun rẹ si dabi ọwọ́ ewurẹ ti o dubulẹ ni Gileadi.

O. Sol 6

O. Sol 6:1-10