O. Sol 5:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn oluṣọ ti nrìn ilu kiri ri mi, nwọn lù mi, nwọn sì ṣa mi lọgbẹ, awọn oluṣọ gbà iborùn mi lọwọ mi.

O. Sol 5

O. Sol 5:5-13