O. Sol 2:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Olufẹ mi dabi abo egbin, tabi ọmọ agbọnrin: sa wò o, o duro lẹhin ogiri wa, o yọju loju ferese, o nfi ara rẹ̀ hàn loju ferese ọlọnà.

O. Sol 2

O. Sol 2:8-17