O. Sol 2:16-17 Yorùbá Bibeli (YCE) Olufẹ mi ni temi, emi si ni tirẹ̀: o njẹ lãrin awọn lili. Titi ìgba itura ọjọ, titi ojiji yio fi salọ