O. Sol 1:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Máṣe wò mi, nitori pe mo dú, nitori pe õrùn ti bojuwò mi: awọn ọmọ iyá mi binu si mi; nwọn fi mi ṣe oluṣọ ọgba-ajara; ṣugbọn ọgba-ajara temi li emi kò tọju.

O. Sol 1

O. Sol 1:1-12