O. Daf 89:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun li o ni ìbẹru gidigidi ni ijọ enia mimọ́, o si ni ibuyìn-fun lati ọdọ gbogbo awọn ti o yi i ká.

O. Daf 89

O. Daf 89:1-16