O. Daf 87:1-4 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. IPILẸ rẹ̀ mbẹ lori òke mimọ́ wọnni.

2. Oluwa fẹ ẹnu-ọ̀na Sioni jù gbogbo ibujoko Jakobu lọ.

3. Ohun ogo li a nsọ niti rẹ? Ilu Ọlọrun!

4. Emi o da orukọ Rahabu ati Babeli lãrin awọn ti o mọ̀ mi: kiyesi Filistia ati Tire, pẹlu Etiopia: a bi eleyi nibẹ.

O. Daf 87