O. Daf 87:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. IPILẸ rẹ̀ mbẹ lori òke mimọ́ wọnni.

2. Oluwa fẹ ẹnu-ọ̀na Sioni jù gbogbo ibujoko Jakobu lọ.

O. Daf 87